Roseline Osipitan
Ìrísí
Olorì Roseline Omolará Òṣípìtàn jẹ́ aláàkóso ìṣòwò Nàìjíríà àti ọmọ ọba ilẹ̀ Yorùbá. Ó jẹ́ ààrẹ àti alága ẹgbẹ́ olómìnira ti Petroleum Marketers Association of Nigeria's Women Association. Ó sì tún jẹ́ Olùdásílẹ̀ ti First Royal Oil and Gas. Òun ló mú oyè ti yèyé ọba ti ìlú ìtori dání.
Ìgbésí Ayé
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Olòrì Roseline Omolará Òṣípìtàn ní ìpínlẹ̀ Òǹdó ti ilẹ̀ Nàìjíríà. Òṣípìtàn ń ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí alákòóso ìṣòwò ní ilé - iṣẹ́ epo ni ilẹ̀ Nàìjíríà níbi tí ó tí jẹ́ lára alága obìnrin alákọ̀ọ́kọ́. Ó jẹ́ aya Ọmọba Bọ́la Òṣípìtàn[1][2] [3] [4] [4]
Àwọn Ìtọ́ka Sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Roseline Osipitan shines on - The Nation". Latestnigeriannews.com. Retrieved 2018-12-09.
- ↑ "Omolara Osipitan puts best foot forward". Africanewshub.com. Archived from the original on 2023-04-05. Retrieved 2022-07-11.
- ↑ Audu, Adetutu (30 November 2014). "Roseline Osipitan shines on". The Nation Nigeria. Retrieved 9 December 2018.
- ↑ 4.0 4.1 "The Senator Ajibola and Princess Rose Osipitan Children’s nuptial people are dying to read on this blog + Groom’s Dad is a 4th term Senator and Bride’s mum an oil baroness …How Sweet Sensation joined them together". Asabeafrioka.com. Archived from the original on 2018-08-27. Retrieved 2022-07-11.