Russo-Ukrainian War

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ogun Russo-Ukrainian je ogun ti Russia,Belarus ati Ukraine lowosi. Russia, ati Belarus l'egbe kan ati Ukraine l'egbe miran. Rogbodiyan yii bere ni osu February, 2014 leyin Isote ti Iyi, leyin ti otun dojuko ipo Crimea ati awon abala Dobeas, t'amo kariaye ni abala ti Ukraine. Rogbodiyan pelu afikun Crimea mo Russia (2014), ogun ni Donbas (2014-present), awon isele ogagun, ogun t'ayelujara, ati edofu t'oselu de. Nigba ti yo ma fi ilowosi re pamo, Russia se atiliyein t'ologun de fun awon oloto ni Donbas. Pelu pe o ti oni ogun nla ni l'eti aala lati opin 2021. Russia se ifilole igbogun ti (asekale nla) Ukraine ni ojo 24th February,2022.