Jump to content

Ruti Aga

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ruti Aga
Ruti Aga – Tokyo Marathon (2019)
Òrọ̀ ẹni
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiopian
Ọjọ́ìbí16 Oṣù Kínní 1994 (1994-01-16) (ọmọ ọdún 30)
Sport
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Marathon, Half marathon
Turned pro2016

Ruti Aga ni a bini ọjọ kẹrin dinlogun, óṣu January ni ọdun 1994 jẹ elere sisa ti ọna jinjin ti órilẹ ede Ethiopia. Ruti yege ninu ere awọn óbinrin ti ọdun 2019 ninu Marathon ti ilẹ Tokyo[1][2][3].

Ni ọdun 2012, Aga gba ami ẹ̀yẹ ti silver ninu idije agbaye ti junior ere sisa to waye ni Barcelona, Spain. Ni ọdun 2013, Arabinrin pari pẹlu ipo karun ninu idije ere sisa ti awọn óbinrin ti IAAF agbaye cross country to waye ni Bydgoszcz, Poland. Ni ọdun 2019, Aga kopa ninu idije ere sisa agbaye ayẹyẹ marathon ti awọn obinrin[4]. Ni ọdun 2022, Ruti kopa ninu Marathon ti Chicago ninu ere sisa fun Wakati 2:21:41[5].

  1. • Birhanu Legese and Ruti Aga to defend their titles at the Tokyo Marathon
  2. Tokyo Marathon Winner
  3. Ruti AGA Profile
  4. women’s marathon at the World Championships
  5. Elite Runners Women Chicago Marathon