Sa'id ti Egypt
Sa'id ti Egypt | |
---|---|
Orí-ìtẹ́ | 13 July 1854 – 17 January 1863 |
Ìsìnkú | Hosh al-Basha, Imam-i Shafi'i Mausoleum, Cairo, Egypt |
Aṣájú | Abbas I of Egypt |
Arọ́pọ̀ | Isma'il Pasha |
Consort to | Inji Hanim Melekber Hanim |
Ọmọ | Mohamed Toussoun Pasha Mahmoud Pasha |
Bàbá | Mohammed Ali Pasha |
Ìyá | Ayn al-Hayat Qadin |
Mohamed Sa'id Pasha (Ède Larubawa: محمد سعيد باشا, Èdè Turkey: Mehmed Said Paşa, ọjọ mẹta dinlogun, óṣu March, ọdun 1822 – ọjọ mẹta dinlogun.January, ọdun 1863) jẹ Wāli ti Egypt ati Sudan lati ọdun 1854 de 1863, eyi ni to ri fealty ti arakunrin naa mi si Ottoman Sultan ṣugbọn pẹlu óminira ti a ko fojuri[1]. Iṣẹ Suez Canal bẹrẹ lati oludari Sa'id.
Itan Igbesi Àye Sa'id
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Sa'id jẹ ọmọkunrin kẹrin ti Muhammad Ali Pasha, Sa'id jẹ ọmọ ilẹ french to si kawe ni ilẹ Paris[2].
Labẹ idari Sa'id, óriṣiriṣi ofin, ilẹ ati owo ilẹ lowa[3].Sa'id fi ọwọ si dida ati kikọ canal ni ọjọ kaarun, óṣu January, ọdun 1856. Iwadi ọdun 1886 royin Sa'id gẹgẹbi onifari, ẹni to gbafẹ ati ọlọgbọn, arakunrin naa maa ṣalejo awọn arinrin ajo[4].
Baba Sa'id kogun ja Sudan ni 1821 to si ma ko ẹru pẹlu Awọn ologun. Ikogu ja awọn ẹru yii yatọ si Sudan, Kordofan ati Ethiopia. Sa'id fin ofin lelẹ lori fifagile kikogun ja ilu[5]. Awọn óniṣowo oko ẹru kọ ti ikun si ofin yi. Nigbati iyan owu bẹrẹ, owu ti ilẹ Egypt labẹ idari Sa'id jẹ ibi ta lo fun mills ti Europe. Labẹ idari Sa'id, agbara awọn Sheikh dikun ti awọn ikogun ja nkan isin ti Bedouin dinkun. Ni ọdun 1854, Sa'id da ile ifowopamọ ti Egypt silẹ́, lẹyin naa loda line ti Khedivial Mail[6]. Ni ọdun 1863, Sa'id ku ti Nephew rẹ Ismail ṣe lede toripe ọmọ rẹ Ahmed ku latari iṣẹlẹ jamba. Mediterranean port ti Port Said Ni a sọ lóruko Sa'id. Sa'id fẹ̀ iyawọ meji, Inji Hanim pẹlu ọmọkunrin Ahmed Sherif Pasha ati Melekber Hanim pẹlu ọmọkunrin meji Mahmoud Bey, ati Mohamed Toussoun Pasha. Sa'id ni wọn sin si Hosh al-Basha the Royal Mausoleum ti Imam al-Shafi'i, Cairo, Egypt.
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Sa'id of Egypt, the Glossary". Unionpedia, the concept map. 1910-05-06. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "Saʿīd Pasha Ottoman Viceroy of Egypt, 19th Century Ruler". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "Sa'id of Egypt Biography - Wāli of Egypt and Sudan (1822–1863)". Pantheon. 2023-08-21. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "PASHA, Saïd, Mohammed". napoleon.org. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ Movement, Nasser Youth (2022-05-10). "Mohammed Said Pasha". Nasser Youth Movement. Retrieved 2023-08-26.
- ↑ "RCIN 2914535 - Muhammad Said Pasha, Viceroy of Egypt". Royal Collection Trust. Retrieved 2023-08-26.