Saadatu Hassan Liman
Ìrísí
Saadatu Hassan Liman jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti ilé-ẹ̀kọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Ìsìláàmù tó sì tún jẹ́ ọ̀gá àgbà ní Yunifásítì Ìpínlẹ̀ Nasarawa ní Ìlú Keffi.[1]
Ó gba ìwé-ẹ̀rí àkọ́kọ́ rẹ̀ nínú ìmò Ìslàmí ní Yunifsaiti Jos ní ọdún 1998.
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Saadatu Hassan Liman becomes NSUK VC - first female in 22 years - TheCable Lifestyle