Saidat Adegoke

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Saidat Adegoke
Personal information
Ọjọ́ ìbí24 Oṣù Kẹ̀sán 1985 (1985-09-24) (ọmọ ọdún 38)
Ibi ọjọ́ibíIlorin, Kwara
Club information
Current clubLugano
Senior career*
YearsTeamApps(Gls)
2011–2012FCF Como 2000
2008–2009Milan
National team
2010Nigeria
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only.
† Appearances (Goals).

Sàìdát Adégòkè, tí a bí ní ọjọ́ kerìnlélógún, Oṣù Kẹsàn-án (Oṣù Òwewè), ọdún un 1985 ní ìlú Ìlorin, Ìpínlẹ̀ Kwara, Nigeria, jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]

Iṣẹ re[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọdún 2007, Adégòkè bẹ̀rẹ̀ sí ní ń gbá bọ́ọ̀lù fún Rẹ́mọ Queens láti ìlu rẹ̀ Nàìjíríà, ní ipele Serie A ti Orílẹ̀-èdè Italy fún ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ACF Trento.

Lẹ́yìn Serie A àkọkọ tí ó kópa fún Trento, ó gbá bọ́ọ̀lù wọlé sínú àwọ̀n lẹ́ẹ̀meta nínú ìgbà mẹ́rìndínlógún tí ó kópa. Ní Oṣù kẹjọ (Oṣù Ògún) ọdún 2008, ó kọjá sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù ACF Milan.[2]

Ní Milan, ìtẹ̀síwájú bá a. Nígbà tí ó má a fi di ọdún 2011, ó gba bọ́ọ̀lù wọ'lé sí'nú àwọ̀n ní'gba ogún-ó-lé-kan nínú ìgbà méjìléláàdóta tí ó kópa.

Ní ìgbà tí eré bọ́ọ̀lù bẹ̀rẹ̀, ní bíi ọdún 2011 si 2012, ó kọjá sí ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù FCF Como 2000.[3]

Láti ọdún 2010, ó wà nínú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù orílẹ ède Nàìjíríà ti àwọn Obìnrin. [4]

Awọn itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]