Sandra Ezekwesili

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Sandra Ezekwesili
Sandra at Cool FM Praise Jam, 2015 (2).jpg
Sandra at Cool FM Praise Jam, 2015
Ọjọ́ìbíJune 4 1993 Port Harcourt, Rivers State, Nigeria
IbùgbéLagos, Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gígaEnugu State University of Science and Technology
Iṣẹ́Broadcast Journalist / Media Personality
Ìgbà iṣẹ́2009 - present
Gbajúmọ̀ fúnHosting Cool FM, Port Harcourt's Breakfast show Good Morning Nigeria on Cool FM, Port Harcourt, and Nigeria Info, Lagos's drive time show, "Hard Facts".
Websitesandrasezekwesili.wordpress.com

Sandra Sopuluchukwu Ezekwesili jẹ oniroyin àti agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ilẹ̀ Nàìjíríà. Òun ni atọkun fún eto ìròyìn Drive Time ati ètò Hard Facts lóri Nigeria Info 99.3 Fm ni Ìpínlè Èkó ni Nàìjíríà.

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé, ètò-ẹ̀kọ́ àti Iṣẹ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí sì ìpínlè Port Harcourt ni Nàìjíríà, òun nikan ni obìnrin láàrin àwọn ọmọ mẹ́ta tí àwọn òbí rẹ bí.[1] Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ NAOWA Nursery and Primary School ni Enugu fún ẹ̀kọ́ ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ rẹ̀.[2] Iṣẹ́ agbejọ́rọ̀ ni Sandra fẹ́ ṣe tẹ́lẹ̀, ṣùgbọ́n wọn kò mú fún imọ ẹ̀kọ́ òfin ni ilé ẹ̀kọ́ gíga, kàkà bẹ́ẹ̀, ìmọ̀ ibi ibanisoro ni wọ́n mú fún. Ní ìgbà tí ó wà ní ilé ẹ̀kọ́ gíga, ó lọ sí ilé iṣẹ́ tí Enugu State Broadcasting Service (ESBS), níbẹ̀ ni ó ti kọ iṣẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́.[3] Lẹ́yìn tí ó ṣe tán ní ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Enugu State University of Science and Technology, ní bi ti o ti kà ìwé imọ ibanisoro, ó siṣẹ́ fún Katsina TV ni Nàìjíríà, lèyín tí ó kúrò ní bẹ̀, ó ti si ṣé fún Radio Bayelsa àti Ray Power Fm ni Yenogoa. Ó bẹẹ rẹ̀ sì ni si ṣé fún Cool Fm ni oṣù kẹta ọdún 2013.[4] Wọn faa kalẹ fun ẹ̀bùn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ obìnrin tó tayọ julọ ni ọdún 2014. Ó gbà ẹ̀bùn láti ọwọ́ Stefano Piotti Foundation ni ọdún 2015.[5] Ní oṣù kọkànlá ọdún 2018, ó kúrò láti Cool Fm sì Nigeria Info 99.3 Fm. Òun sì ní atọkun ètò Hard Facts tí wọn máa ń ṣe ní ìrólé láti ago mẹta di ago méje.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Coolfm - Nigeria". www.coolfm.ng. Retrieved 11 September 2017. 
  2. http://www.ph-microscope.com/you-know-their-voicesbut-how-well-do-you-know-these-oaps-sandra-ezekwesili/
  3. "You know their voices…but how well do you know these OAPs (Sandra Ezekwesili)?". 26 February 2016. Retrieved 11 September 2017. 
  4. Wikina, Ebenezar (3 December 2014). "TEDxYouth@OrdinanceRoad: How We Put West Africa on the Map". Retrieved 11 September 2017. 
  5. "Steph Foundation - Team". www.stephfoundation.com. Retrieved 11 September 2017.