Saworoide

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Saworoide jẹ́ eré àgbéléwò tí Tunde Kelani darí àti tí Mainframe Films and Television Production ṣe àgbéjáde rẹ̀ ní ọdún 1999.


Àkójọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Saworoide ṣe àfihàn ètò àṣà yorùbá pípẹ́ kan ní ìlú Jogbo níbi tí èèyàn kò lè jẹ oba láìjé  pé èèyàn tó tọ́ lú ìlu saworoide.[1]

Àwọn tó kópa[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Ayantunji Amoo
  • Kunle Bamtefa
  • Kayode Olaiya
  • Yemi Shodimu
  • Kola Oyewo
  • Lere Paimo
  • Bukky Wright
  • Khabirat Kafidipe
  • Kunle Afolayan

Àwọn ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Eniola, Babatunde (3 January 2014). "THE MYSTERY `SAWOROIDE`". Rough Africa. Retrieved 5 November 2015. 

Kíkà síwájú[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

ìjápọ Ìta[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]