Shavkat Mirziyoyev
Ìrísí
Shavkat Miromonovich Mirziyoyev Шавкат Мираманович Мирзиёев | |
---|---|
Fáìlì:Mirziyoyev.jpg | |
Ààrẹ Uzbekistan | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 14 December 2016 | |
Alákóso Àgbà | Abdulla Aripov |
Asíwájú | Islam Karimov |
Alákóso Àgbà Uzbekistan | |
In office 11 December 2003 – 14 December 2016 | |
Ààrẹ | Islam Karimov |
Deputy | Ergash Shoismatov |
Asíwájú | O‘tkir Sultonov |
Arọ́pò | Abdulla Aripov |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | July 24, 1957 Jizzakh Region, Uzbek SSR, Soviet Union |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Self-Sacrifice National Democratic Party (until 2008) Uzbekistan National Revival Democratic Party |
Shavkat Miromonovich Mirziyoyev (lede Rosia Шавкат Мираманович Мирзиёев Shavkat Miramanovich Mirziyoyev loun lo) (ojoibi 1957[1]) ni Alakoso Agba orile-ede Uzbekistan.[1][2] O je didaloruko sipo yi latowo Aare Islam Karimov ni ojo 12 Osu Kejila 2003, beeni ileasofin Usbeki si faramo. O ropo Alakoso Agba O‘tkir Sultonov to je lilekuro. Igbakeji re ni Ergash Shoismatov.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Brief profile of Mirziyoyev Archived 2007-11-16 at the Wayback Machine., Radio Free Europe/Radio Liberty.
- ↑ "South Korea, Uzbekistan Sign Uranium Deal", RadioFreeEurope/RadioLiberty, September 25, 2006.