Shure Demise
Ìrísí
Shure Demise Ware tí a bí ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kìíní, ọdún 1996 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa nínú eré-ìdárayá eré-sísá ní orílẹ̀-èdè Ethopia, tó sì ti kópa nínú ìdíje lóríṣiríṣi.[1]
Àṣeyọrí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọdún 2015, Demise kópa nínú Marathon ti Dubai tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹrin[2]. Ní ọdún 2015, Demise kópa nínú Marathon ti ilẹ̀ Boston tó sì parí pẹ̀lú ipò kẹjọ[3]. Ní ọdún 2019, Demise kópa nínú Marathon ti àwọn obìnrin ní ìdíje àgbáyé lórí eré sísá tó wáyé ní Doha, Qatar[4].
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Shure DEMISE - Profile". worldathletics.org. 1996-01-01. Retrieved 2023-04-10.
- ↑ Dubai Marathon
- ↑ Boston Marathon
- ↑ Women Marathon