Jump to content

Sinke Biyadgilgn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sinke Dessie Biyadgilgn ni a bini ọdun 1995 jẹ Akọṣẹmọṣẹ elere sisa lóbinrin ta bisi órilẹ ede Ethiopia to sin gbe ni Washington, D .C[1].

Ni 2018, Sinke kopa ninu Marathon ti ibeji pẹlu wakati 2:33:04 nibi to ti gba ẹbun owo ti $7,500[2][3]. Ni ọdun 2016, Sinke kopa ninu ere sisa ti mile maarun pẹlu wakati 26:51[4].

  1. Sinke Profile
  2. Twin Cities Marathon
  3. Twin Cities Marathon
  4. Dc Road Runners