Jump to content

Slindile Nodangala

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Slindile Nodangala
Ọjọ́ìbíSlindile Nodangala
23 Oṣù Kẹfà 1972 (1972-06-23) (ọmọ ọdún 52)
Durban, South Africa
Orílẹ̀-èdèSouth African
Iṣẹ́
  • Actress
  • Singer
  • voice-over artist
Ìgbà iṣẹ́1989–present
Àwọn ọmọ2

Slindile Nodangala (bíi ni ọjọ́ kẹtàlélógún oṣù kẹfà ọdún 1972) jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè South Áfríkà tí ó gbajúmọ̀ fún ipá Ruby Dikobe tí ó kó nínú eré Generations. Nodangala dàgbà sí ìlú Durban, ìyá bàbà rẹ̀ ló sì tọju rẹ̀. Nodangala tí bí ọmọ méjì.[1]

Nodangala ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Lyceum Theater ni ìlú London ni ọdún 2001. Ó kópa nínú eré Generations láti oṣù kẹfà ọdún 2011 di oṣù kejìlá ọdún 2014.[2] Ó ti farahàn nínú eré Izulu lami ni ọdún 2008 àti The Lion King.[3][4]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Slindile Nodangala - Actress". Woman Online Magazine. 28 May 2013. 
  2. "Slindile Nodangala". Tvsa.co.za. Retrieved 2015-06-26. 
  3. "Slindile Nodangala". IMDb.com. Retrieved 2015-06-26. 
  4. "Slindile Nodangala". LinkedIn. Retrieved 2015-06-26.