Sofiat Arinọla Obanishola

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Sofiat Arinọla jẹ ikan lara awọn elere badminton lobinrin ni orilẹ ede Naigiria ti a bini ni 16, óṣu september ni ọdun 2003. Arabinrin na ti kopa ni ere idijè Badminton ni kakiri orilẹ ede ati ókè okun. [1].

Àṣeyọrì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  • Sofiat gba Bronze medal ati silver ni Game awọn ọdọ ilẹ Afirica ni ọdun 2018[2]
  • Èlere na gba bronze medal ni Casablanca, ilu Morocco ni Game awọn ọdọ ilẹ Afirica ni ọdun 2019[3]

Itọkasì[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. https://www.the-sports.org/sofiat-arinola-obanishola-badminton-spf611584.html
  2. https://guardian.ng/sport/team-nigeria-wins-africa-schools-badminton-championship/
  3. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2020-07-05. Retrieved 2022-05-21.