Special Anti-Robbery Squad
Ìrísí
Special Anti-Robbery Squad tí òpòlopò ènìyàn mó sí SARS jé aka Olopa télè rí tí a dá kalè ní odun 1992 láti dojuko iwuwa odaran [1] sùgbón tí opin dé bá ní ojó kokanla, osù kewa, odun 2020(11 Oct. 2020)[2] léyìn iwode ifehonuhan láti owo awon odo Nàìjíríà tí a mo sí iwode "fopin sí SARS"
Iwode fopin sí SARS
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwon odo Nàìjirià bèrè iwode ifehonuhan náà bèrè ní 0ct 2020 [3] ni ìgbà tí fiimu bí àwon olopa SARS kan se pa okunrin kan àti bi won se gbe okò rè lo farahan lórí ìkànnì ayelujara [4] èyi mú ìjoba apapo Nàìjirià fopinsi eka SARS ni Oct 11, 2020 [5]
Àwon Ìtókasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Akinwotu, Emmanuel (2020-10-11). "Nigeria to disband Sars police unit accused of killings and brutality". the Guardian. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ Busari, Stephanie (2020-10-11). "Nigeria dissolves controversial police unit accused of brutality". CNN. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ Ayitogo, Nasir (2021-10-20). "#EndSARS Anniversary: One year after, what has happened to protesters’ five-point demand?". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ Jones, Mayeni (2021-10-06). "Nigeria’s #EndSars protests: What happened next". BBC News. Retrieved 2022-03-08.
- ↑ "Why Nigeria's #EndSARS movement is more than a call to end police brutality". World Economic Forum. 2020-12-21. Retrieved 2022-03-08.