Jump to content

Steve Agee

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Steve Agee
Ọjọ́ìbíSteven Douglas Agee
26 Oṣù Kejì 1969 (1969-02-26) (ọmọ ọdún 55)
Riverside, California, U.S.
Iṣẹ́Comedian, actor, writer
Ìgbà iṣẹ́2000–present

Steven Douglas Agee ( /ˈˌ/; tí wọ́n bí ní February 26, 1969) jẹ́ apanilẹ́rìn-ín ti Orílẹ̀ èdè America, òǹkọ̀wé àti olórin. Ó tún máa ń tẹ dùrù pẹ̀lú ẹgbẹ́ olórin lóríṣiríṣi, ní ọdún 1990,[1] ó sì ti fìgbà kan ṣẹrẹ́ pọ̀, pẹ̀lú Brendon Small.[2][3]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Interview with Comedian Steve Agee | PSYCHIC GLOSS MAGAZINE". Archived from the original on 2021-01-21. Retrieved 2023-08-21. 
  2. "Dethklok on Facebook". Facebook. Archived from the originalFree access subject to limited trial, subscription normally required on 2022-04-30. Àdàkọ:CbignoreÀdàkọ:User-generated source
  3. "Scab, by Steve Agee".