Suleiman Bogoro
Ìrísí
Ọ̀jọ̀gbọ́n (Prof.) Suleiman Elias Bogoro jẹ́ ọ̀gá àgbà (Executive Secretary) tí àjọ ìjọba àpapọ̀ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà fún owó ìrànwọ́ fún àwọn Ifáfitì Tertiary Education Trust Fund, (TETFUND). [1] Ààrẹ Muhammadu Buhari yàn án sípò yìí lọ́dún 2019. Ó ti wà nípò yìí bákan náà lọ́dún 2014 sì 2016. [2]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "BIOGRAPHY OF TETFUND SECRETARY: PROFESSOR SULEIMAN ELIAS BOGORO". UNIVERSITY OF IBADAN. Retrieved 2020-01-06.
- ↑ Okeke, Chidimma C. (2019-01-22). "Why Prof Bogoro was reinstated at TETFund – Daily Trust". Daily Trust. Archived from the original on 2019-01-23. Retrieved 2020-01-06.