Sunday Jack Akpan
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Sunday jack akpan)
Sunday Jack Akpan (orúkọ ìbisọ rẹ ni Ikot Ide Etukudo, 1940) jẹ́ Agbẹ̀gí kéré tí orílé èdè Nàìjíríà tí wón ń pé ní èdè gèésì ni "the contemporary African equivalent of the medieval artisan".[1] ó jẹ́ gbajúmò fún iṣé rẹ̀, iṣé ère èyí tí ó máa ń ló Sìmẹ̀tì cement, èyí tí ó máa ń fí ń gbé àwọn èrè ìbílè fún àwọn ẹni Oyè àti àwọn èèyàn jàǹkàǹjàkàǹ, àti àwọn ojú ìbòjú grave art, lẹ́yìn náà ní yóò wá kún ọdà; ọ tí ṣé àwọn iṣé ère lórísiríri, èyí tí ó wà fún títà commercial arts, àwọn bí àlùfáà ìjọsìn àti àwọn èèyàn jàǹkàǹ ní àwùjọ.[2] àwọn iṣé èrèle rẹ̀ wá ni ìfihàn ni Venice Biennale[1] àti ní gbàgede Centre Pompidou ni Paris, àti àwọn gbàgede ìfihàn míìràn.[1] àwọn iṣé rè náà ni Horniman Museum ni London.[2]
=Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 Sunday Jack Akpan: Contemporanea arti E culture – Milan – sculpture exhibition – Brief Article | ArtForum | Find Articles at BNET
- ↑ 2.0 2.1 "Cement Sculpture in Nigeria and its Antecedents". rawvision.com. Archived from the original on 9 March 2012. Retrieved 20 April 2015. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)