Tosin Jegede
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Tósìn Jẹ́gẹ́dẹ́)
Tosin Jegede tí wọ́n bí lọ́dún 1980 [1] jẹ́ gbajúmọ̀ ọ̀dọ́mọdé obìnrin olórin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.
Ìgbésí ayé rẹ̀ àti iṣẹ́ orin rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lọ́dún 1986 ló gbé àwo orin rẹ̀ àkọ́kọ́ jáde ti o pè ní Children Arise. Ọmọ ọdún márùn-ún ló wà ní àkókò náà. Lẹ́yìn náà ó gbé àwo orin méjì mìíràn jáde, tí ó pè ní: Leaders of Africa àti Children of Africa lọ́dún 1989 àti 1992.[2] Lẹ́yìn èyí, ó gbọ̀nà òkè òkun lọ láti lọ kàwé sì í. Ó kàwé gboyè nínú ìmọ̀ Business Decision and Analysis láti University of Bristol, ní London, ó ṣíṣe fún ìgbà díẹ̀ ni United Kingdom kí ó tó padà sí Nàìjíríà lọ́dún 2008.[3][4][5][6][7]
Ìyá Tósìn kú lọ́dún 2012. Lẹ́yìn náà, ó dá ilé isẹ afowóṣàánú silẹ tí ó pè ní One Book One Child, ó ń fi èyí ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọdé Nàìjíríà.[2]
Àṣàyàn àwo àwo orin rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Children Arise (1985)
- Leaders of Africa (1989)
- Children of Africa (1992)
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nigerian kid music stars and where they are now". Premium Times Nigeria. 2020-05-31. Retrieved 2020-11-13.
- ↑ 2.0 2.1 Old Skool child celebrity Tosin Jegede explains pet project, One Book, One Child ‘Music can wait for now’. Encomium. http://encomium.ng/old-skool-child-celebrity-tosin-jegede-explains-pet-project-one-book-one-child-music-can-wait-for-now/.
- ↑ Benjamin Njoku. "I left the country to escape from being kidnapped ON SEPTEMBER 8, 2012". The Guardian. http://www.vanguardngr.com/2012/09/i-left-the-country-to-escape-from-being-kidnapped/.
- ↑ "Tosin Jegede finally released from 25 year music contract with Polygram Records". Nigerian Entertainment Today. http://thenet.ng/2014/04/tosin-jegede-finally-released-from-25-year-music-contract-with-polygram-records/.
- ↑ Thisweek. 1988. p. 45. https://books.google.com/books?id=iEsuAQAAIAAJ&q=C.
- ↑ Noah A. Tsika (2015). Nollywood Stars: Media and Migration in West Africa and the Diaspora:New Directions in National Cinemas. Indiana University Press. ISBN 978-0-253-0158-08. https://books.google.com/books?id=BjF3BwAAQBAJ&pg=PA223&dq=.
- ↑ Abisola Akawode. "Why Child Singers Never Succeed In Nigerian Music Industry". Leadership News. http://leadership.ng/entertainment/460210/why-child-singers-never-succeed-in-nigerian-music-industry.