TY Bello

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Toyin Ṣókẹ́fun-Bello (ọjọ́ ìbí - ọjọ́ kẹrinla oṣù kíní ọdún 1978[1]), tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí TY Bello, jẹ́ ọmọ orile-ede Naijiria, akọrin ni, a si tun maa ṣe agbekale orin fun awon elomiran lati kọ ọ jade, ayaworan ni, o si tun je eleyinju aanu. Kí o to di akoko ti TY Bello bẹrẹ ise adase rẹ̀, o ti wa pelu ẹgbẹ olorin ẹ̀mí ti a n pe ni Kush ki ẹgbẹ naa to ko'gba w'ọle. TY Bello jẹ ọmọ ẹgbẹ agbarijọ awọn oluyaworan ni orile-ede Naijiria, ti a n pe ni Depth of Field[2] TY Bello di gbajugbaja nipase awon orin adakọ re ti o se bii "Greenland (Ilẹ ọlọra)", "Ekundayọ", "This Man (Okunrin Yi)", "Freedom (Ominira)" ati "Funmiṣe".

  1. https://www.informationng.com/2018/01/photographer-ty-bello-celebrates-40th-birthday-lovely-pictures.html
  2. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named KonnectAfrica