Tadelech Bekele
Ìrísí
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kẹrin 1991 |
Sport | |
Orílẹ̀-èdè | Ethiopia |
Erẹ́ìdárayá | Athletics |
Event(s) | Long-distance running |
Tadelech Bekele ni a bini ọjọ kọkanla, óṣu April, ọdun 1991 jẹ elere sisa lóbinrin ti ilẹ Ethiopia[1].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ni ọdun 2012, Tadelech yege ninu Idaji Marathon ti České Budějovice pẹlu wakati 1:10:54. Ni ọdun naa, Arabinrin naa yege ninu Prague Grand Prix to jẹ ere ti ẹgbẹrun marun pẹlu wakati 15:48. Ni 2014, Tadelech yege Idaji Marathon ti Berlin pẹlu wakati 1:10:05[2][3]. Ni ọdun 2014 ati 2015, Tadelech kopa ninu Marathon ti Berlin to si pari pẹlu ipo kẹrin. Ni ọdun 2017 ati 2018, Tadelech yege ninu Marathon ti Amsterdam [4] Ni ọdun 2018, Tadelech kopa ninu Marathon ti London to si gbe ipo kẹta pẹlu wakati 2:21:40[5].
Itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Profile
- ↑ "Berlin Marathon". Archived from the original on 2023-04-01. Retrieved 2023-04-01.
- ↑ Berlin Marathon
- ↑ Amsterdam Marathon
- ↑ London Marathon