Teni Aofiyebi
Ìrísí
Teni Aofiyebi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Teniade Aofiyebi |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Actress, businesswoman |
Teniade Aofiyebi jẹ́ òṣèré[1] àti oníṣòwò[2] lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[3] Ó kópa nínú eré Mirror in the Sun ní ọdún 1984 títí di ọdún 1986.[4] Ní ọdún 2003, ó kópa nínú eré For Better, For Worse.[5] Ní ọdún 2005, ó kópa nínú eré Prince of Savannah, èyí tí Bayo Awala ṣe adarí fún.[6] Ní ọdún 2013, ó kópa nínú eré ìfẹ́ Flower Girl, èyí tí Michelle Bello ṣe adarí rẹ̀.[7] Ní ọdún 2015, ó kópa nínú eré Royal Castle tí ó sọ̀rọ̀ nípa ọ̀dalẹ̀, ẹ̀tàn, jìbìtì àti ìfẹ́.[8] Ní oṣù karùn-ún ọdún 2014, Aofiyebi dá ilé iṣẹ́ TKM Essentials kalẹ̀.[9] Ní ọdún 2019, ó ṣe adájọ́ fún ìdíje obìnrin tó rẹwà jùlọ fún àwọn odi.[10] Ó jẹ́ mọ̀lẹ́bí fún Funlola Aofiyebi-Raimi.[11]
Àwọn Ìtókàsi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Aniemeka, Chuka (6 July 2013). "Teni Aofiyebi ages gracefully". Online Nigeria. Archived from the original on 3 July 2018. https://web.archive.org/web/20180703131408/https://news2.onlinenigeria.com/news/general/302944-teni-aofiyebi-ages-gracefully.html. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ Olapoju, Kolapo (6 August 2014). "One-on-one: 50 entrepreneurs selected for mentorship in Mara Mentor programme". Ynaija. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "Svend Juncker: Turmoil, drama of tracing ancestral roots". Vanguard. 5 December 2018. https://www.vanguardngr.com/2018/12/svend-juncker-turmoil-drama-of-tracing-ancestral-roots-1/. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "Funlola Aofiyebi: Five Things You Should Know About The Star". Heavy NG. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ Ajayi, Babs (17 March 2015). "A STRANGE AND FASCINATING NATION: MY EARLY YEARS IN NIGERIA (Concluded)". Nigeria World. Archived from the original on 11 November 2020. https://web.archive.org/web/20201111110405/https://nigeriaworld.com/feature/publication/babsajayi/031705.html. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "Shijuwomi, Behold My Redeemer". Rssing.com. 17 June 2015. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "FAB Teaser: ‘Flower Girl’". FAB Magazine. 14 December 2012. http://fabmagazineonline.com/fab-teaser-flower-girl/. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "Watch Chris Attoh, Deyemi Okanlawon, Gloria Young & more in new Telenovela". Pulse. 19 September 2015. Archived from the original on 11 November 2020. https://web.archive.org/web/20201111104514/https://www.pulse.ng/entertainment/movies/royal-castle-watch-chris-attoh-deyemi-okanlawon-gloria-young-and-more-in-new/ypgvz9h. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ "‘Why I went into rental business’ – TENI AOFIYEBI". Encomium. 21 May 2014. https://encomium.ng/why-i-went-into-rental-business-teni-aofiyebi/. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ Emmanuel, Daniji (1 November 2019). "Nigeria Holds First Beauty Pageant for Deaf Girls Nov.1". Inside Business. https://insidebusiness.ng/89287/nigeria-holds-first-beauty-pageant-for-deaf-girls-nov-1/. Retrieved 9 November 2020.
- ↑ Suleiman, Yemisi (30 August 2009). "I've always wanted to educate and entertain people - Funlola Aofiyebi-Raimi". Vanguard. Retrieved 29 September 2013.