Teresa (2010 film)
Ìrísí
Teresa | |
---|---|
Adarí | Juan Pablo Ebang Esono |
Olùgbékalẹ̀ | National Library of Equatorial Guinea |
Òǹkọ̀wé | Guillermina Mekuy Mba Obono |
Àwọn òṣèré | Elena Iyanga Betty K.B. Dina Anguesomo |
Ìyàwòrán sinimá | Juan Pablo Ebang Esono |
Déètì àgbéjáde | 2010 |
Àkókò | 34 min. |
Orílẹ̀-èdè | Equatorial Guinea |
Èdè | Portuguese |
Teresa, jẹ́ fíìmù oníṣókí kan ti ọdún 2010 tí wọ́n ṣe ní Equatoial Guinea tí olùdarí rẹ̀ n ṣe Thato Rantao Mwosa, èyí tí ààjo ilé-ìkàwé orílẹ̀-èdè Equatorial Guinea ṣe onígbọ̀wọ́ rẹ̀.[1] Guillermina Mekuy Mba Obono lẹni tí ó kọ ìtàn eré náà. Àwọn olùkópa rẹ̀ pẹ̀lú Elena Iyanga, Betty KB, àti Dina Anguesomo. Eré náà jẹ́ àkọ́kọ́ fíìmù Equatorial Guinea tí wọ́n ma ṣe tó sì gùn níwọ̀nba.[2]
Àwọn olùkópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Elena Iyanga as Teresa
- Betty K.B.
- Dina Anguesomo
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Die besten Filme aus Äquatorialguinea". moviepilot. Retrieved 20 October 2020.
- ↑ "“Teresa”, the first medium-length film produced by the National Library: a story based on actual events.". Government of Equatorial Guinea. 20 August 2010. Archived from the original on 21 May 2012. Retrieved 7 October 2020.