Jump to content

The Hard Case

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
The Hard Case
AdaríGuy Ritchie
Olùgbékalẹ̀Nick Burgess-Jones
Òǹkọ̀wéGuy Ritchie
Àwọn òṣèréDarren Spencer
Benedick Bates
Wale Ojo
Ìyàwòrán sinimáJan Pester
OlóòtúMatthew Glen
Ilé-iṣẹ́ fíìmùSpidercom Films
Déètì àgbéjáde1995
Àkókò20 minutes
Orílẹ̀-èdèUnited Kingdom
ÈdèEnglish

The Hard Case jẹ́ fíìmù orílẹ̀-èdè Britain tí ó jáde ní ọdún 1995. Guy Ritchie ni ó kọ fíìmù yìí tí ó sì tún darí rẹ̀. Àwọn akópa fíìmù yìí ni Darren Spencer tí ó ṣe The player, Benedick Bates tí ó ṣe player àti Wale Ọjọ́ tí ó ṣe gambler. Fíìmù ogún ìṣẹ́jú yìí gbéwọ̀n ju fíìmù Ritchie kan tí í ṣe Lock, Stock and Two Smoking Barrels.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. The Hard Case, retrieved 2018-11-04