Jump to content

The Tourist (2021 film)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ere onise The Tourist je sinima ti orile-ede Russia[1] ti Andrey Batov se adari re, ti Sergei Shcheglov si je onkotan ere naa. Lare Osere lami-laka ti o won kopa ninu re ni Sergey Pavlov, ti osi je Olu eda-itan ti Aleksey Shevchenkov, Richard Sseruwagi, Marika Lindström, Sten Ljunggren ati Philip Lithner ni won je amugba-legbe Olu eda-itan.

  1. "The Tourist (TV Mini Series)". IMDb. 2021-10-21. Retrieved 2021-10-21.