Jump to content

Tigist Assefa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Assefa at a meeting in Reims, France in 2013
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Tigist Assefa Tessema
Ọmọorílẹ̀-èdèEthiopian
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹta 1994 (1994-03-28) (ọmọ ọdún 30)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Long-distance running
Achievements and titles
Personal best(s)
  • 800 metres
  • 800 m: 1:59.24 (Lausanne 2014)
  • Marathon: 2:15:37 (Berlin 2022)

Tigist Assefa Tessema ni a bini ọjọ keji dinlọgbọn, óṣu March, ọdun 1994 jẹ elere sisa ọna jinjin[1]. Lẹyin ti arabinrin naa kopa ninu marathon to waye ni oṣù kẹrin, ọdun 2022 lo gbiyanju si lori iṣẹju meji dinlogun. Tigist kopa ninu Marathon ti Berlin nibi to ti gbe ipo karun[2][3][4].

Ni ọdun 2013, Assefa gba ami ẹyẹ ti ọla ni idije junior ti ilẹ afirica. Ni ọdun 2014, Óṣu August Tigist gbe ipo kẹrin ninu idije ilẹ Afirica lori ere sisa to waye ni Marrakesh, Morocco. Ni ọdun 2016, Tigist kopa ninu idije inule ti agbaye to waye ni Portland, Oregon nibi to ti pari 800m ni abala akọkọ[5]. Ni ọdun 2022, Tigist jẹ óbinrin akọkọ lati ja íṣẹju aya meji fun 800m ati 2:20 fun Marathon[6]. Ni óṣu March, ọdun 2022 Assefa kopa ninu Marathon ti Riyadh to way ni ilu Saudi Arabia nibi to ti pari pẹlu ipo keje pẹlu wakati 2:34:01[7]. Ni ósu April, ọdun 2022 Assefa yege ninu ayẹyẹ ikọsilẹ ti óju ọna ti Adizero to waye ni Ilu Germany.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Tigist ASSEFA Profile
  2. Berlin Marathon
  3. Tigist Assefa (2:15:37) Stuns World at 2022 Berlin Marathon
  4. Tigist Assefa of Ethiopia scores women’s win in 2:15:37
  5. 800m
  6. Assefa, who ran the 800m at the Rio Olympics in 2016, also became the first woman in history to break two minutes for 800m and 2:20 for the marathon.
  7. Riyadh Marathon