Tilburg

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tilburg kerk

Tilburg jẹ ìlú kàn ní gúúsù tí orílẹ̀-ède Netherlands. O fẹ́rẹ̀ tó ènìyàn eègbá lè ní ọkẹ mọ̀kanla (222,000) tó ngbé níbẹ (2021). Tilburg ní òkìkí nítorí Schrobbeler rẹ, tó jẹ́ ọtí líle tó wà fún mímú. Ni Tilburg bákan náà , Ilé-ẹ̀kọ́ gíga Tilburg wa níbẹ.

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]