T. M. Aluko
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Timothy Mofolorunso Aluko)
Timothy Mofolorunso Aluko (14 June, 1918 - 1 May, 2010) je olukowe ara ile Naijiria[1][2].
Ígbèsi Àyè Àràkunrin naa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aluko jẹ ọmọ yóruba ti à bini Ilesha ni ilẹ naigiria. Arakunrin naa jẹ óriṣiri ipó to si fẹyinti ni ọdun 1978. T. M. Aluko ku ni ọjọ akọkọ, óṣu May ni ọdun 2010 ni ilu èkó[3][4].
Ẹkọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Aluko naa kẹẹkọ ni College ijọba ni Ibadan ati College ni Yaba, Ipinlẹ Eko lẹyin naa lo lọsi ilè iwè giga ti London lati kẹẹkọ lori Imọ Civil engineering ati town planning. Ni ọdun 1976, Àrakunrin naa gba doctorate lori imọ municipal engineering[5].
Ami Ẹyẹ ati Idanilọla
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Alukó gba ami ẹyẹ ti OBE ni ọdun 1963 pẹlú ami ẹyẹ ti OON ni ọdun 1964[6][7][8].
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ https://blerf.org/index.php/biography/aluko-dr-timothy-mofolorunso/
- ↑ https://www.jrank.org/literature/pages/3154/T-M-Aluko-(Timothy-Mofolorunse-Aluko).html
- ↑ https://www.britannica.com/biography/T-M-Aluko
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-11-24. Retrieved 2022-11-24.
- ↑ https://www.oxfordreference.com/view/10.1093/oi/authority.20110803095406365
- ↑ https://web.archive.org/web/20100505141014/http://234next.com/csp/cms/sites/Next/Home/5562814-146/t.m_aluko_is_dead__.csp
- ↑ https://allafrica.com/stories/200807130068.html
- ↑ http://www.gcimuseum.org/content/aluko-timothy-mofolorunso