Tirunesh Dibaba

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tirunesh Dibaba
Dibaba at the 2008 Bislett Games
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ ìbílẹ̀Xurunash Dibaabaa
Ọjọ́ìbí1 Oṣù Kẹfà 1985 (1985-06-01) (ọmọ ọdún 38)
Bekoji, Arsi Province, Derg
Height166 cm
Weight50 kg
Spouse(s)
Sileshi Sihine (m. 2008)
Sport
Orílẹ̀-èdèEthiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)5,000 metres, 10,000 metres, half marathon, marathon
Achievements and titles
Personal best(s)
  • 5000 m: 14:11.15[1] (5000 metres#Women
  • 2nd fastest all-time)
  • 10,000 m: 29:42.56[2] (10,000 metres#Women
  • 7th fastest all-time)
  • Marathon: 2:17:56[3] (Marathon#All-time top-25 marathoners
  • 16th fastest all-time)

Tirunesh Dibaba ni a bini ọjọ akọkọ, óṣu June, ọdun 1985 jẹ elere sisa lóbinrin to dalo ri ọna jinjin ati ere ti oju ona oke okun[4].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tirunesh kopa ninu ere olympic to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura lẹẹmẹta[5]. Ni ọjọ kẹfa, ósu june, ọdun 2008, Dibaba kopa ninu ere ti Bislett to waye ni Oslo ti mita ẹgbẹrun maarun pẹlu wakati 14:11.15. Ni ọdun 2008, Tirunesh kopa ninu Olympics ti summer ti mita ẹgbẹrun mẹwa pẹlu wakati 29:54.66. Ni ọdun 2008, Dibaba ni IAAF sọ ni Elere sisa ti ọ̀dun naa. Ni ọdun 2010, Dibaba kopa ninu idije ti ilẹ Afirica ti mita ti ẹgbẹrun mẹwa pẹlu wakati 31:51.39 to waye ni Nairobi. Ni ọdun 2012, Dibaba kopa ninu olympics ti summer ti London pẹlu wakati 30:20.75 ti mita ẹgbẹrun mẹwa. Ni ọdun 2013, Tirunesh kopa ninu idije agbaye ti mita ẹgbẹrun mẹwa to waye ni Moscow[6]. Ni ọdun 2014, Tirunesh kopa ninu marathon ti London to si pari pẹlu ipo kẹta pẹlu wakati 2:20:35. Ni ọdun 2016, Dibaba kopa ninu Olympics ti summer ni Rio de Janeiro ni mita ẹgbẹrun mẹwa. Ni óṣu August, Dibaba kopa ninu idije agbaye ti London ti mita ẹgbẹ̀run mẹwa to si gba ami ẹ̀yẹ ti ọla ti silver pẹlu iṣẹju aya 46.37. Ni ọdun 2017, Dibaba kopa ninu marathon ti Chicago to si gba ami ẹyẹ ti ọla ti wura pẹlu wakati 2:18:30[7]. Ni óṣu september, ọdun 2018, Dibaba kopa marathon ti Berlin pẹlu wakati 2:18:55 to si pari pẹlu ipo kẹta. Ni óṣu October, ọdun 2018, Dibaba kopa ninu idaji marathon ti Delhi to si pari ipo kẹfa. Ni óṣu january, ọdun 2023, Tirunesh kopa ninu Idaji Marathon ti Houston to si pẹ̀lu wakati 71:35[8]

Itọkasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Peter Larsson (2 July 2017). "All-time women's best 5000m". Track and Field all-time Performances. Retrieved 2 July 2017. 
  2. Peter Larsson (28 June 2017). "All-time women's best 10 000m". Track and Field all-time Performances. Retrieved 2 July 2017. 
  3. Peter Larsson (17 June 2017). "All-time women's best marathon". Track and Field all-time Performances. Retrieved 2 July 2017. 
  4. Tirunesh Dibaba
  5. Olympics
  6. World Championship
  7. Chicago Marathon
  8. Half Marathon Houston