Tisha Campbell
Tisha Campbell | |
---|---|
Campbell in November 2018 | |
Ọjọ́ìbí | Tisha Michelle Campbell 13 Oṣù Kẹ̀wá 1968 Oklahoma City, Oklahoma, U.S. |
Ẹ̀kọ́ | Newark Arts High School |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1977–present |
Ọmọ ìlú | Newark, New Jersey, U.S. |
Olólùfẹ́ | Duane Martin (m. 1996; div. 2018) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Musical career | |
Irú orin | |
Instruments | Vocals |
Labels | |
Associated acts | Tichina Arnold, Keith Washington |
Tisha Michelle Campbell (ojoibi October 13, 1968) je osere, akorin ati onijo ara Amerika. Won bi ni Oklahoma City, Oklahoma, o si dagba ni New Jersey, o bere ere filmu re ni 1986 ninu filmu alawada Little Shop of Horrors, o si kopa leyin igbana ninu ere dirama ile-isr telifisan NBC to n je Rags to Riches (1987–1988).
Campbell kopa ninu awon filmu bi School Daze (1988), Rooftops (1989), Another 48 Hrs. (1990), Boomerang (1992), ati Sprung (1997). O gba ipeloruko ebun Independent Spirit Award for Best Supporting Female fun isere re ninu filmu komedi odun 1990 to n je House Party, o tun kopa leyin na ninu apa keji ati apa keta filmu na; House Party 2 (1991), ati House Party 3 (1994).
Lori telifisan, Campbell sere gege bi Gina Waters-Payne ninu ere komedi telifisan Fox to unje Martin from 1992 to 1997 ati gege bi Janet "Jay" Marie Johnson-Kyle ninu ere komedi telifisan ABC to n je My Wife and Kids (2001–2005), eyi to gba ebun NAACP Image Award for Outstanding Actress in a Comedy Series fun. Leyin na o tun kopa ninu awon ere telifisan bi Rita Rocks (Lifetime, 2008–2009), The Protector (Lifetime, 2011), ati Dr. Ken (ABC, 2015–2017).