Tobiloba Ajayi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tobiloba Ajayi
Ọjọ́ìbíOluwatobiloba Ajayi
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́Writer, Lawyer, activist

Tobiloba Ajayi jẹ́ agbejọ́rọ̀ ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó ní àrùn Cerebral palsy.

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ajayi ni ọmọ kẹrin láàárín àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí rẹ bí. Àwọn òbí rẹ kò kọ́kọ́ fẹ́ ran lọ sí ilé ẹ̀kọ́ nítorí àìlera tí ó ní. Àìlera yí kò fun ni àǹfààní láti lè jókòó, dúró tàbí rìn. Ó bẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ rẹ̀ nígbà tí ó wà ní ọmọ ọdún mẹta. Ó gboyè gíga jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Hertfordshire nínú ìmò òfin àgbáyé.[1]

Iṣẹ́[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ ni Mobility Aid and Appliance Research and Development Center.[2] Ó sì wà láàárín àwọn tí ó ṣe òfin fún àwọn alábọ̀ ara ní ìpínlẹ̀ èkó.[3] Ó gbà Mandela Washington Fellowship ni ọdún 2016.[4] [5]Ní oṣù kìíní ọdún 2017, ó si ṣẹ́ pelu Benola Cerebral Palsy Initiatives. Ní oṣù kejì ọdún 2018, ó gbé ètò kàn kalẹ̀ tí ó fi ṣe ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ọmọ tí ó bá ní àrùn Cerebral Palsy.[6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Adetorera, Idowu. "‘There is life after disability’". The nation. Retrieved 17 January 2017. 
  2. Adebayo, Bose. "MAARDEC’s Ms wheelchair contest gives voice to the physically challenged". Vanguard. Retrieved 17 January 2017. 
  3. Osonuga, Freeman. "A Nigerian Lawyer With Cerebral Palsy: My Encounter". The Huffington Post. Retrieved 17 January 2017. 
  4. Precious, Drew. "The Presidential Precinct Announces 2016 Mandela Washington Fellows". Presidential Precinct. Retrieved 17 January 2017. 
  5. Precious, Drew. "Tobiloba Ajayi". Presidential Precinct. Retrieved 16 November 2019. 
  6. Dark, Shayera (27 February 2018). "Nigerians with disabilities are tired of waiting for an apathetic government". Bright magazine. https://brightthemag.com/health-nigeria-disability-rights-activism-96aa2cfef5f2. Retrieved 11 November 2019.