Toka McBaror
Ìrísí
Toka McBaror | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Toka McBaror Kaduna, Nigeria |
Iṣẹ́ |
|
Ìgbà iṣẹ́ | 1998-present |
Gbajúmọ̀ fún |
|
Awards | See below |
Toka McBaror jẹ́ aṣagbátẹrù fíìmù tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ó sì tún jẹ́ olùdarí fíìmù[2][3][4] and music video director[5][6] tí wọ́n bí, tí ó dàgbà, tí ó sì ń gbé ní Ìpínlẹ̀ Kaduna, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àmọ́ tí ó wà láti Ìpínlẹ̀ Delta.[7] Ó gbà àmì-ẹ̀yẹ fún "Kada River" ní ọdún 2018 Toronto International Nollywood Film Festival ní ìlú Canada,[8][9] àmì-ẹ̀yẹ mẹ́fà fún fíìmù Lotanna ní 2017 Golden Movie Awards.[10][11]
Ó tún gba àmì-ẹ̀yẹ fún fíìmù tó dára jù lọ, olùdarí fíìmù tó dára jù lọ, láti 2018 Toronto International Nollywood Film Festival, TINFF, tó wáyé ní Toronto, Canada.[12] [13]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Funke Akindele makes directorial debut in Mo Abudu's 'Your Excellency'". August 6, 2019.
- ↑ Kehinde, Opeyemi (August 21, 2019). "Ali Nuhu, Ramsey Nouah, Chika Lann feature in 'The Millions'". Daily Trust. Retrieved October 4, 2020.
- ↑ "Blossom Chukwujekwu News". Retrieved October 4, 2020.
- ↑ "Somkhele Iyamah, Adesua Etomi, Adunni Ade attend old school themed premiere". Pulse. April 9, 2017. Archived from the original on July 16, 2018. Retrieved October 4, 2020.
- ↑ "Teni - "Power Rangers" | Download MP3 « tooXclusive". June 13, 2019. Archived from the original on November 28, 2021. Retrieved September 2, 2023.
- ↑ "'Under the Sky' with Praise". October 12, 2020. Archived from the original on November 28, 2021. Retrieved September 2, 2023.
- ↑ Offiong, Adie Vanessa (April 6, 2019). "I Thought I Would End Up A Basketballer – Toka Mcbaror". Daily Trust. Retrieved October 5, 2020.
- ↑ Husseini, Shaibu (September 16, 2017). "A huge world premiere for Toka Mcbaror's 'Kada River' in Toronto". Retrieved October 2, 2020.
- ↑ "Alter Ego, Kada River… Movies to be screened at Nollywood Travel Film Festival". News Agency of Nigeria. August 31, 2017. Retrieved October 4, 2020.
- ↑ "Nollywood director, Toka McBaror bags six awards at the Golden Movie Awards 2017". Sagagist. July 26, 2017. Retrieved November 7, 2020.
- ↑ "Epic Drama ‘Lotanna’ Goes on Amazon Prime Video – THISDAYLIVE". www.thisdaylive.com. Retrieved 2022-07-19.
- ↑ "Nigerian Movie, The Island, Wins Best African Film Award at 2018 TINFF". August 18, 2019. Archived from the original on October 8, 2020. Retrieved October 2, 2020.
- ↑ "Ghana Earns 14 Nominations At 2018 African Film Awards London". Ghafla!. September 26, 2018. Retrieved November 3, 2020.