Jump to content

Àwọn obìnrin alámì pupa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Tolu Olukayode Odugbemi)
Àwọn obìnrin oní àmì òsìṣé Pupa

Àwọn obìnrin alámì pupa {WiR} , jẹ́ àgbékalè iṣé láti dí àlàfo láàrin okunrin sí obìnrin lórí ẹ̀rọ ayélújara ti Wikipédia. Àwọn obìnrin alámi pupa jé àkànṣe iṣé WikiProject lóri ẹ̀rọ ayéluja yanju idojukọ lati ṣẹda awọn nkan nipa awọn obinrin olokiki ti ko si nibe lowolowo bayii.. Ifiyesi lati mo nipa awon akole ti o sonu ni lati wo awon hyperlink pupa ninu awon ti won ti seda won tele

Women in Red presentation by Roger Bamkin, Wikimania 2017