Tosin Lawson

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Tosin Lawson jẹ́ onímọ̀ nipa oge àti olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ tí wọ́n ń pè ní African design. Tosin kàwé gboyè àkọ́kọ́ ní Unifásítì ti Nottingham nibi tí ó ti kọ́ nípa ìmọ̀ bí a ṣe lè pèlò nka. Ó jẹ́ ìkan lára àwọn tí ó ń gbé oge ìbílẹ̀ larugẹ. Iṣẹ́ àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ ṣe ni ẹ̀gbà ọrùn tí a fi àǹkárá ṣe ṣẹ̀ṣọ́ sí.[1] Iṣẹ́ Tosin ni ṣe pẹ̀lú bí a ṣe lè fi ankara ṣẹ̀ṣọ́ àti bí a ṣe tún ṣe lè fi ṣe àwọn ohun èlò míràn bíì àpamọ́n, bàtà àti ègbà ọrùn.[2]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Meet The Founder of African Things - Exclusive Interview". Bellafricana. 2017-07-05. Archived from the original on 2018-05-17. Retrieved 2018-07-11. 
  2. "African things: Meet Tosin Lawson, the young ankara entrepreneur - The Website for African Entrepreneurs". The Website for African Entrepreneurs. 2016-01-22. Retrieved 2018-07-11.