Jump to content

Trans Sahara trade

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán tí ó ń ṣàfihàn máàpù bí wọ́n ti ń ṣe òwò ní trans Sahara (1862)
building kan ní Oualata, southeast Mauritania
Bilma oasis ni northeast Niger, pẹ̀lú Kaouar escarpment ni ìsàlẹ̀

Trans-Saharan trade tàbí ìṣòwò láàrín Sahara nílò ìrìn-àjò kọjá Sahara láàrín Ìwọ̀-oòrùn, Central, Ìlà-orùn àti Àríwá Áfíríkà. Lákòkò tí ó ti ń wà lati àwọn àkókó tí wọ́n pè ní Prehistoric times, àwọn àkókó ìṣààjúu, èyí tí ó jẹ́ ìgbà kàn ti iṣowo gbòòrò wà ní òkè tente láti ọ̀rúndún kẹ́jọ títí di ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndun kẹ́tàdínlógún.


Sahara yìí tí fi igba kan ri bíí Sahara Aláwọ̀ ewé rí, agbègbè tí ó yàtọ púpọ̀ sí Sahara òde òni. Ní igbà kàn rí, ní Ẹgbẹ̀rún ọdún méje sẹ́yìn kí a tó bí Jésù ní ìṣẹ́ daran-daran àwọn ohun Ọ̀sìn bí Ẹran ewúrẹ, Àgùntàn, tí wà ní àwọn orílé èdè bí Libya àti Algeria, pẹ̀lú isẹ́ fífi Amọ̀ mọ nǹkan. Lèyìn Ẹgbẹ̀rún ọdún mẹ́rin sí Mẹ́ta àbọ̀ ní iṣẹ́ dída ẹran Màálù ni Central Sahara ní Ahaggar bẹ̀rẹ̀.

Àwọn àwòrán àpatà ìyàlẹ́nu (ní 3500 si 2500 BC) ní àwọn ààyè tí ó gbẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, ṣe àfihàn àwọn òdòdó àti àwọn ẹranko tí kò sí ní agbègbè aginjù Òde òní.[1]

  1. Shillington, Kevin (1995). History of Africa (Second ed.). New York: St. Martin's Press. p. 32. ISBN 0-333-59957-8. https://archive.org/details/historyofafrica00shil.