Jump to content

Àdéhùn Versailles

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Treaty of Versailles)
Treaty of Versailles
Treaty of Peace between the Allied and Associated Powers and Germany

Cover of the English version
Signed
Location
28 June 1919
Versailles, France
Effective
Condition
10 January 1920
Ratification by Germany and three Principal Allied Powers.
Signatories Àdàkọ:Country data Weimar Republic

 British Empire
Fránsì France
 Italy
 Japan
 United States


Unofficial Ally  Belgium

Depositary French Government
Languages French, English
Wikisource logo Treaty of Versailles at Wikisource
The Signing of the Peace Treaty of Versailles

Àdéhùn Versailles ni ikan ninu awon adehun alaafia ti o mu opin de ba Ogun Agbaye kiini. O pagi agi di kikede tabi sisigun larin ile Jamani ati awon ilu Alagbara Agbaye. O di fifonte-lu nipa fifowobowe ni ojo kejidinlogun osu Okudu odun 1919(28 June 1919), ni eyi ti o se deede odun marun leyin siseku-pa Archduke Franz Ferdinand.