Troian Bellisario
Ìrísí
Troian Avery Bellisario (a bí i ní ọjọ́ 28 oṣù ọ̀wàrà, ọdún 1985) jẹ́ òṣèrébìnrin orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà . Ó kẹ́kọ̀ọ́ gboyè jáde ní ilé-ẹ̀kọ́ gíga University of Southern California, ní ọdún 2010, ó gba ipò tí ó fún un ní ọ̀nà àbáyọ gẹ́gẹ́ bi Spencer Hastings nínú eré ìtàgé atòtẹ̀léra Freeform tí orúkọ eré náà ń jẹ́ Pretty Little liars (ní ọdún 2010 sí ọdún 2017), èyí tí ó sọ ọ́ di ìlú-mọ̀-ọ́n-ká káàkiri àgbáyé, tí ó sì gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmì-ẹ̀yẹ àti ìdánimọ̀ àmì-ẹ̀yẹ àti ìdánimọ̀.
Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Bellisario wọ́n sì tọ́ ọ ní ìlú Los Angeles. Àwọn òbí rẹ̀ méjèèjì Deborah pratt àti Donald P. Bellisario olùṣe-àgbéjáde