Ilé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti United States House of Representatives)
Ilé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà United States House of Representatives | |
---|---|
116th United States Congress | |
Àmì ọ̀pá-áṣẹ Ilé àwọn Aṣojú | |
Àsìá Ilé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà | |
Type | |
Type | Lower house of the United States Congress |
Term limits | None |
History | |
New session started | Oṣù Kínní 3, 2019 |
Leadership | |
Structure | |
Seats | 435 voting members 6 non-voting members 218 for a majority |
Political groups | Majority (232)
Minority (198)
Other (1)
Vacant (4)
|
Length of term | 2 years |
Elections | |
Varies in 5 states
Plurality voting in 45 states | |
Last election | November 6, 2018 |
Next election | November 3, 2020 |
Redistricting | State legislatures or redistricting commissions, varies by state |
Meeting place | |
House of Representatives Chamber United States Capitol Washington, D.C. United States of America | |
Website | |
house.gov |
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀ Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà |
---|
|
Ilé àwọn Aṣojú Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà (The United States House of Representatives ní èdè Gẹ̀ẹ́sì) ni ilé aṣofin kékeré ní Kọ́ngrẹ́ẹ̀sì Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà; Ilé àwọn Alàgbà ni Ilé aṣòfin àgbà. Lápọpọ̀ àwọn méjéèjì jẹ́ ilé-aṣòfin oníléìgbìmọ̀-méjì (bicameral legislature) fún Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.