Jump to content

Yunifásítì ìlú Ilorin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti University of Ilorin)
Senate Building Yunifásítì ìlú Ilorin
Yunifásítì ìlú Ilorin

Yunifásítì ìlú Ilorin jẹ́ yunifásítì tí ìjọba kan tí ó wà ní ìlú Ilorin, ìpínlè Kwárà, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A dá yunifásitì ìlú Ìlorin kalè ni odún 1975 [1]. Orúko daríYunifásitì Ìlorin lówólówó ni Ojogbon Wahab Olasupo Egbewole[2]. Yunifásitì Ilorin ní olé ní aadota egbèrún akeko [3] o si tun ní olé ni egbèrún meedogun hectare ile(15, 000 hectares), èyi tí ó mú won jẹ́ Yunifásitì tí ó ní ilè jù ní orílè-èdè Nàìjíríà [3].





  1. "University of Ilorin". Times Higher Education (THE). 2021-11-21. Retrieved 2022-03-02. 
  2. https://punchng.com/just-in-unilorin-appoints-new-vice-chancellor/
  3. 3.0 3.1 Olusunle, Tunde (2021-11-20). "The Unilorin 'better by far' basket and one bad apple". TheCable. Retrieved 2022-03-02.