Jump to content

Victor Boniface

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia

Victor Boniface
Personal information
Full name Victor Okoh Boniface
Date of birth 23 December 2000 (age 22)
Place of birth Akure, Ondo State, Nigeria
Height 1.90 m (6 ft 3 in)
Position(s) Forward
Team information
Current team Bayer Leverkusen
Number 22
Youth career
–2019 Real Sapphire
Senior career*
Years Team Apps (Gls)
2019–2022 Bodø/Glimt 48 (13)
2022–2023 Union SG 37 (9)
2023– Bayer Leverkusen 13 (8)
International career
2023– Nigeria 5 (0)
*Club domestic league appearances and goals, correct as of 23:43, 25 November 2023 (UTC)

‡ National team caps and goals, correct as of 19 November 2023

Victor Okoh Boniface

ti wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélólógún, oṣù Kejìlá ọdún 2000. Jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọwọ́ iwájú fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Bayer Leverkusen àti tí ikọ̀ super eagle ti ilẹ̀ Nàìjíríà.

Victor Boniface

[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀][àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Bodø/Glimt[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Boniface tọwọ́ bòwé fún ikọ̀ Bodo/Glimt láti inú ikọ̀ Real Sapphire ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2019. Ó ní ìfarapa lẹhin bí ọ̀sẹ̀ méjì tí ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ Glimt. Léyìí tí ó mú kí ó má lè kópa nínú sáà ọdún 2019.

Wọ́n mu Boniface sí inú ikọ̀ super eagle àwọn tí ọjọ́ orí wọn ò jú ogún ọdún lọ nínú ìdíje kọ́ọ̀pù ilẹ̀ Áfríkà tí ọjọ́ orí wọn kò ju ogún ọdún lọ. Ṣùgbọ́n ó ní láti kústo

úrò nínú ikọ̀ náà látàrí ìfara. Ní oṣù kẹsàn-án ó kópa fún ìgbà àkókò fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù rẹ̀. a rẹ̀