Jump to content

Victoria Albis

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Victoria Albis (d. after 1777), jẹ́ obìnrin ọmọ Senagal tí ó alágbára nítorí ó fẹ́ àwọn aláṣẹ àwọn òyìnbó tí ó sì jogún wọn. [1] Ó wà lára àwọn gbajúmọ̀ obìnrin tí ó lágbára nítorí ó fẹ́ àwọn òyìnbó alágbára ní erékùṣù Gorée láàárín àwọn elédè Faransé Senegal. Ó jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn gbajúmọ̀ alágbára obìnrin lásìkò náà ni Senegal.

Òun ni ó kọ́ Henriette-Bathily Women's Museum.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Gorée: the island and the Historical Museum. Abdoulaye Camara, Institut fondamental d'Afrique noire Cheikh Anta Diop, Joseph-Roger de Benoist, Musée historique du Sénégal.IFAN-Cheikh Anta Diop, 1993