Vivian Yusuf

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Vivian Yusuf
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Vivian Aminu Yusuf
Ọmọorílẹ̀-èdèNàìjíríà Nàìjíríà
Ọjọ́ìbí8 Oṣù Kẹjọ 1983 (1983-08-08) (ọmọ ọdún 40)
Weight78 kg (172 lb)
Sport
Erẹ́ìdárayáJudo
Event(s)78 kg
Coached byBashir Bassey (national)

Vivian Aminu Yusuf ni a bini ọjọ kẹjọ, óṣu kẹjọ(ogún) ni ọdun 1983, ó jẹ ọkan ninu awọn óbinrin to kopa ninu ere judo ni órilẹ ede Naijiria ninu abala idaji heavyweight[1][2][3].

Àṣèyọri[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Vivian gba ami ọla ti idẹ ni ere ti gbogbo ilẹ Afirica ni ọdun 2007 to waye ni Algiers ati Idije Judo ti ilẹ Afirica ni ọdun 2008 to waye ni Agadir, Morocco[4]. Vivian kopa ninu ere olympics ti summer nibi ti arabinrin naa ti ṣóju Naigiria ninu XXIX Olympiad ni Beijing, China nibi to ti kopa ninu idaji Heavyweight (78kg)[5][6][7].

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Vivian Yusuf Biography
  2. Vivian Yusuf Judoka
  3. Judo - Vivian Yusuf
  4. African Championships Agadir - Event
  5. Olympic Game Results in 2008
  6. Beijing Olympics Games in 2008
  7. Nigerian judoka to start 4 nation tours as Olympic warmup