Jump to content

Wikipedia:Àwon olóòtú

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àkékúrús:
WP:Àwon olóòtú
WP:AO
Ẹnikẹ́ni lè gbé Wikipedia sí àtálẹwọ́ wọn àti ìwọ náà. Gbogbo ohun tí o ní lati ṣe ni kí o ṣe àtúnṣe sí àyọkà.

Àwon olóòtú jẹ́ àwon tó ń kọ àyọkà Wikipedia láì gbowó, wọ́n yàtọ̀ sí àwon tó ń ka àyọkà lásán. Ẹnikẹ́ni—àti ìwọ— lè di olóòtú Wikipedia nípa ṣíṣe àtúnṣe tí wọ́n bá rí ohun tó ń fẹ́ àtúnṣe. Fún ẹ̀kọ́ nípa bí o ṣe lè ṣe àtúnṣe sí àyọkà, yẹ ẹ̀kọ́ ṣíṣe àtúnṣe sí àyọkà wò. Oríṣiríṣi iṣẹ̀ ni àwon olóòtú Wikipedia ń ṣe.