Wikipedia:AO
Ìrísí
Èyí ni Ojúewé fún ìmọ nípa Àwon olóòtú Wikipedia |
Àwon olóòtú jẹ́ àwon tó ń kọ àyọkà Wikipedia láì gbowó, wọ́n yàtọ̀ sí àwon tó ń ka àyọkà lásán. Ẹnikẹ́ni—àti ìwọ— lè di olóòtú Wikipedia nípa ṣíṣe àtúnṣe tí wọ́n bá rí ohun tó ń fẹ́ àtúnṣe.