Jump to content

Ogun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti War)
Ala-ilẹ kan nibiti awọn aririn ajo ti ba ni ita ilu kekere kan.
Àyọkà yìí jẹ mọ́ nípa ìjà jàgídíjàgan. Fún ìtumọ̀ míràn, ẹ wo: Ogun (ìṣojútùú).

Ogun Ẹkú dédé àsìkò yìí ẹ̀yin ọmọ ogun. Ẹ jọ̀wọ́ ẹ jẹ́kí á tún bọ̀ sọwọ́pọ̀ láti gbé ògo ilẹ̀ Yorùbá ga.Inù mi dùn púpọ̀ sí àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ẹ̀tí kẹ́kọ̀ọ́ tí wọ́n sì jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá yálà nílẹ̀ Yorùbá tàbí ní òkè òkun bá lè bẹ̀rẹ̀ láti máa kọ́ ọ̀pọlọ̀pọ̀ nínú àwọn àròkọ wọn ní èdè abínibí wà nítorí òní kọ́ àmọ́ nítorí ọjọ́ ọ̀la kí àwọn ọmọ tí wọn kò ì tíì bí lè rí nnkan kà nípa gbogbo ohun mère mère tí ó n sẹlẹ̀ jákè jádò àgbáyé.

Tí a bá wo àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n sẹ̀sẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sì ní máa gbérí níwọ̀n ọgbọ́n ọdún sẹ́yìn a ri wí pé púpọ̀ nínú wọn ni wọn fi èdè abínibí kọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ wọ́n, kòsí iṣẹ́ìwádìí kan tí wọ́n se tí wọ́n kò kọ ní èdè wọn bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé èdè gẹ̀ẹ́sì ni wọ́n gbà fi ṣe ìwádìí náà. Ó ṣeni láànu láti máa pàdé àwọn ara ilé nílu òyìnbó kí wọ́n máa fara pamọ́ ki a máà ba pè wọ́n ní ọmọ Yorùbá.Ogún lọ́gọ̀ àwọn olùkọ́ni nílu òyìnbó ni wọ́n jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Yorùbá ṣùgbọ́n pẹ̀lú gbogbo akitiyan wọn kò sí ọ̀kan ṣoṣo nínú isẹ́ ìwádìí wọ́n pẹ̀lú aroko tí ó wà ní èdè Yorùbá- Kí ló dé?

Ọ̀rọ́ tán lẹ́nu ṣùgbọ́n ó pọ̀ níkùn,

Títí di ọjọ́ mìíràn ọjọ́ ire, Emi ni tiyín ní tòótọ́, Ọmọba Onanusi Olusegun. Onanusi_olusegun@hotmail.comó

Àkíyèsí pàtàkì - Ti ẹ bá ní ohun láti sọ nípa àròkọ yìí, ẹ̀yin náà lè bọ́sí gbàgede WIKIPEDIA.

Ojúewé yìí ti jẹ́ dídárúkọ fún ìparẹ́ kíákíá.
The reason given is "article is not encyclopedic". If you disagree with its speedy deletion, please explain why on its talk page. If this page obviously does not meet the criteria for speedy deletion, or you intend to fix it, please remove this notice, but do not remove this notice from a page that you have created yourself.

Administrators, remember to check if anything links here and the page history (last edit) before deletion.