Jump to content

Whatsapp

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Whatsapp jé ikanni ibanidore lori èro ayelujara, o gba àwon olumulo rè láyè lati fí òrò ranse si arawon, ó sì tún sé fi se ipe fidio. A lè ló ìkànnì ibanidore WhatsApp lori foonu, komputa tábìlì àti komputa alagbeka. Jan Koum àti Brain Acton(àwon mejeji jé alabasise Yahoo télèrí) lódá Whatsapp kalè ní odun 2009 kí Facebook(tí a mo sí "meta" báyìí) tó ra ní bilionu mọkandilogun dọla($19 billion) ní odun 2014[1] Orílè è

dè India ni oní olumulo WhatsApp topojù, Brazil àti Orílè èdè Amerika sì tele[2]

Awon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Covert, Adrian (2014-02-19). "Facebook buys messaging service WhatsApp for $19 billion". CNNMoney. Retrieved 2022-02-27. 
  2. "fb plans to turn whatsapp into a money making messenger app". Bloomberg. 2020-12-09. Retrieved 2022-02-27.