Wikipedia:Ìṣeìbàjẹ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Wikipedia:Vandalism)

Ìṣeìbàjẹ́ ní à únpè irú ìparẹ́ tàbí ìyípadà àkóónú yìówù tí a mọ̀ọ́mọ̀ ṣe láti mú búburú bá Wikipedia. Ìrú ìṣeìbàjẹ́ tó wópọ̀ jùlọ ní ìrọ́pò ìkọ pẹ̀lú ìranù, orúkọ tàbí àkóónú tí kò ní ìtumọ̀; pípa àkóónú ojúewé rẹ́, àti fífi àwòrán burúkú sínú àwọn ojúewé. A kò ní gba ìṣeìbàjẹ́ ní ààyè!

Ipá inú rere lati ṣe àtúnṣe sí Wikipedia, bótilẹ̀jẹ́pé ó jẹ́ pẹ̀lú àṣìṣe ìgbàgbọ́ tàbi èrò kìí ṣe ìṣeìbàjẹ́.