Wolé Olánipẹ̀kun

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search

Olóye Wọlé Olánipẹ̀kuntí wọ́n bí ní Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kọkànlá ọdún 1951 (November,18th 1951)jẹ́ Adájọ́ ọmọ Yorùbá láti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Òun ni Ààrẹ Ẹgbẹ́ Ìgbìmọ̀ Àwọn Adájọ́ Nigeria Bar Association

Ìgbà èwe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Olóye Wọlé Olánipẹ̀kun lọ sí Ilé-Ìwè Amoye Grammar School ni Íkẹ́rẹ́-Ekiti,Ípìnlẹ́ Ekiti State. Wọlé,parí ẹ̀kọ̀ mewa West Africa School Certificate ni Ilésa Girama kí ó to rékọ́já si gbogbo gbo University of Lagos, Nïbi tï oti gba oyê kèkerê nínú ise òfin.[1][2] A pee si inú îgbîmọ́ àwọn adájọ̀ Call to the bar ni orîlẹ́ èdè Naijiria ni Odún 1976. Ni Odún 1991 ó di Agbẹjọ́ró Àgbà fún Ìpínlẹ̀ Ondo . Ó wa ni Ipó yi fún Odûn Mêjî gbàko. Ni odún 2002, wọ́n yan si ipò gẹ́gẹ́bí Ààrẹ fún Nigerian Bar Association.[3]   .[4] Láti odún 2004 si 2006 ó jé Ògá àgàbà Ìgbìmò àti Olùdárí fún Yunifásítì Ìlú-Ìbàdàn .[5][6]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Wole Olanipekun - INFORMATION NIGERIA". informationng.com. Retrieved 25 April 2015. 
  2. "Alumni, students urge N’Assembly to disregard UNILAG bill". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 25 April 2015. 
  3. "Celebrating Wole Olanipekun at 59 , Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Retrieved 25 April 2015. 
  4. "Sofola emerges Body of Benchers’ chairman". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 25 April 2015. 
  5. John Austin Unachukwu. "UI honours ex-NBA chief Ọlánípẹ̀kun". The Nation. Retrieved 25 April 2015. 
  6. "Forget Past Injustices Olanipekun Tells UI VC, Articles - THISDAY LIVE". thisdaylive.com. Retrieved 25 April 2015.