Workitu Ayanu
Ìrísí
Workitu Ayanu Gurmu ni a bini ọjọ kọkan dinlógun ni ọdun 1987 jẹ elere sisa lóbinrin ilẹ Ethiopia to da lori metres ẹgbẹrun marun[1][2][3].
Àṣèyọri
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Workitu kopa ninu idije Agbaye ti IAAF Cross country pẹlu ipo kẹrin ninu ere junior ti awọn óbinrin ni ọdun 2004 to si gbè pari pẹlu ipo kẹfa ni ọdun 2005 ati 2006[4]. Ni ọdun 2009, Arabinrin naa yege ninu idaji marathon ti Egmond pẹlu wakati 1:16:33. Ni ọdun 2010, Workitu kopa ninu Marathon ti Paris nibi to ti pari pẹlu ipo karun ni wakati 2:29:25[5][6]. Ni ọdun 2011, Workitu kopa ninu Marathon ti ilẹ Rome to si pari pẹlu ipo kẹfa pẹlu wakati 2:29:37.