Yasin Mazhar Siddiqui

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Yasin Mazhar Siddiqui (tí a mọ̀ sí Yasin Mazhar Siddique Nadvi)  (26 December 1944 títídé 15 September 2020) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè India, onimọ̀ ẹ̀kọ́ ti Musulumi Sunni àti onímọ̀ ìjìnlẹ̀ ìwádí ìtàn tí ó sì ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́bí alakoso ẹ̀ka ìmọ̀ nípa Islam ti ilé ẹ̀kọ́ giga ti Mùsùlùmí ní Aligarh.

Yasin Mazhar Siddiqui ni wọ́n bí ní 26 December 1944 ní agbègbè Lakhimpur Kheri ni àpapọ̀ agbègbè India ti Britiko. ó kẹkọ jade nínù ẹ̀kọ́ dars-e-nizami ní ilé ìwé Darul Uloom Nadwatul Ulama ni ọdun 1959, tí ó sì tún kẹkọ gboyè si ninu literaṣo ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Lucknow ní ọdun 1960. Ó kékọ yege ní ilé ẹ̀kọ́ Jamia Millia Islamia ni ọdun 1962 o si gba oyè D.A ní ọdun 1965 ati B.Ed. ní 1966 ní ilé ẹ̀kọ́ kanna. Ní ọdún 1968, Siddiqi gba ìmọ̀ gíga (M.A.), ninú ẹ̀kọ́ iwadi itan, (M.phil.)  ni 1969, o di ọ̀mọ̀wé (PhD) ni ọdún 1975 ní ilé ìwé gíga Musulumi ní Aligarh. Lára àwọn olùkọ́ rẹ̀ ni Abul Hasan Ali Nadwi, K.A Nizami, Abdal-Hafiz Balyawi àti Rabey Hasani Nadwi.

Siddiqui ní wọ́n yan gẹ́gẹ́bí olùrànlówó aṣe'wadi ní ẹ̀ka ìmọ̀ iwadi itan ti Ilé ẹ̀kọ́ gíga Musulumi ti Aligarh ni ọdún 1970. Ó di olùkọ́ iwadi ìtàn ni ọdún 1977, Saiyis Hamid fun ní ìṣípòpadà lọ si ẹ̀ka ikẹkọ nípa Islam. ní ọdun 1983. Ó di ọ̀jọ̀gbọ́n ti ìmọ̀ ẹ̀kọ́ Islam ni ọdún 1991 ó si ṣe adarí ní èka naa laarin ọdun 1997 si 2000. Ni 2001, wọn yan gẹ́gẹ́bí adarí ase'wadi niShah Waliullah ní èka ìmọ̀ ẹ̀kọ́ Islam. Ó gba ìfẹ̀hìnti lẹ́nu iṣẹ́ ni 31 December 2006 sugbọn wọn da duro sí ipo adari awon ase'wadi ni Shah Waliullah fun ọdun mẹwa laarin 2000 si 2010, Ó ṣe àgbékalẹ̀ idanilẹkọ orilẹ ède ati àkójọpọ̀ awọn orílẹ̀ ede nípa ìgbé ayé Shah Waliullah Dehlawi, o sì kọ ìwé méjìdínlógún.

Sidiqui gba àmìẹ̀ye Shah Walliullah karun láti ọwọ ile ẹ̀kọ́ (institute of Objective Studies) ni New Delhi ni 24 September 2005. O papòda ní 15 September 2020.

Iṣẹ́ Àkànṣe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Áwọn ìwé tí a ti ̣ọwọ Siddiqui kọ

  • Tārīkh Tehzeeb-e-Islāmi
  • Ghazwāt ki Iqtesādi Ehmiyat
  • Tawhīd-e-Ilāhi awr mufassirīn-e-girāmi
  • Wahi-e-Hadīth
  • Ehd-e-Nabwi mai Tanzīm-e-Riyāsat-o-Hukūmat
  • The Prophet Muhammad: A Role Model for Muslim Minorities
  • Catalogue of Arabic Manuscripts at the Aligarh Muslim University, published by Al-Furqan Islamic Heritage Foundation in London in 2002.


References

Citations

"Indian scholar for eliminating interest from banking system". The News International. 12 March 2014. Retrieved 15 September 2020.

Nizāmi, Zafar Ahmad. Qalmi khākey (First, 2013 ed.). p. 263.

Muhammad Abdullah. "Professor Yāsin Mazhar Siddīqi ki Sīrat Nigāri". Ziya-e-Tehqeeq. 3 (6): 10. Archived from the original on 16 September 2020. Retrieved 15 September 2020.

"Shah Waliullah Award". iosworld.org. Institute of Objective Studies. Retrieved 15 September 2020.

"معروف مصنف و محقق پروفیسر یسین مظہر صدیقی کا انتقال، علمی حلقہ سوگوار" [Renowned author and researcher Professor Yāsin Mazhar Siddīqi passes away]. Millat Times (in Urdu). 15 September 2020. Retrieved 15 September 2020.

Nizāmi, Zafar Ahmad. Qalmi khākey (First, 2013 ed.). p. 263-264.

Hāfiz Muhammad Sāni (10 November 2019). "Ehd-e-Nabwi mai Tanzīm-e-Riyāsat-o-Hukūmat". Daily Jang (in Urdu). Retrieved 15 September 2020. Ehd-e-Nabwi mai Tanzīm-e-Riyāsat-o-Hukūmat is a magnum opus work of Professor Siddīqi on the administration of Medina State: Hāfiz Muhammad Sāni

Hofmann, Murad Wilfried (May 2007). "The Prophet Muhammad: A Role Model for Muslim Minorities". Journal of Islamic Studies. Oxford University Press. 18 (2): 241-243. doi:10.1093/jis/etm003. JSTOR 26199808.

Bibliography

Nizāmi, Zafar Ahmad. "Professor Yāsin Mazhar Siddīqi". Qalmi khākey (in Urdu) (First, 2013 ed.). New Delhi: Institute of Objective Studies. pp. 263–264. ISBN 978-81-89964-96-2.

Muhammad Abdullah. "Professor Yāsin Mazhar Siddīqi ki Sīrat Nigāri". Ziya-e-Tehqeeq (in Urdu). Government College University Faisalabad: Department of Islamic Studies & Arabic. 3 (6): 9–17. Archived from the original on 16 September 2020. Retrieved 15 September 2020.