Yorùbá fún Sáyẹ́nsì àti Ìṣírò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
  • Slope = Ìtẹ̀
  • Length = Ìbú
  • Volume = Ìkúnsi
  • Mass = Ọ̀pọ̀
  • Time = Àsìkò
  • Distance = Jíjìnàsí
  • Abstract = Àfòyemọ̀
  • Rate = Ratio = Ìpín
  • Degree = Ìyí
  • Breadth = Iro
  • Fraction = Ìdá
  • Number = Nọ́mbà
  • Triangle = Anígunmẹ́ta
  • Motion = Ìgbéra
  • Element = Àpilẹ̀sẹ̀
  • Diameter = Ìlàrin
  • Weight = Ìwúwo
  • Electricity = Ìtanná
  • Electronics = Ẹ̀rọ oníná
  • Electron = Atanná
  • Electric current = Ìwọ́ iná
  • Field = Pápá
  • Electromagnetism = Inágbéringbérin
  • Magnetic field = Pápá gbéringbérin
  • Solution = Ojútùú
  • Solve = S'ojútùú
  • Equation = Ìdọ́gba
  • Equal = Dọ́gba
  • Quantity = Ọ̀pọ̀iye
  • Quality = Àwúlò
  • Property = Àdámọ̀
  • Area = Agbègbè
  • Calculus = Ìsirò kálkúlọ́sì
  • Trigonometry = Ìwọ̀n anígunmẹ́ta
  • Sphere = Roboto
  • Coordinate = Ipòìdojúkọ
  • Surface = Òdeojú
  • Plane = Pẹpẹ
  • Science = Sáyẹ́nsì
  • Average = Àriniye
  • Decimal = Nọ́mbàmẹ́wàá
  • Point = Ojúàmì
  • Heat = Ooru
  • Temperature = Ìgbónásí
  • Planet = Plánẹ́tì
  • Universe = Àgbàlá-ayé
  • Earth = Ilẹ̀-ayé
  • Solar = Tòòrùn
  • Energy = Okun
  • Work = Isẹ́
  • Polygon - Anígunpúpọ̀
  • Physical science = Sáyẹ́nsì àfojúrí
  • Physics = Ìmọ̀ aláfojúrí
  • Acid = Omi-olóró
  • Verb = Ase-ọ̀rọ̀
  • Adverb = Alátise-ọ̀rọ̀
  • Sky = òfuurufú
  • Space = ààyè
  • Alcohol = Otí
  • Alphabet = Títò Lẹ́tà
  • Algebra = Áljẹ́brà
  • Amenities = Amáyédẹ̀rọ̀
  • Anglican = Ìjọ àgùdà
  • Ape = Akítì
  • Velocity =
  • Speed =
  • Cube =
  • Particle =
  • Radius =
  • Density =
  • Matter =
  • Solid =
  • Acceleration =